Wọ́n ju ọmọ 'Yahoo' márùn-ún sẹ́wọ̀n l'Abẹ́òkúta - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, January 17, 2022

Wọ́n ju ọmọ 'Yahoo' márùn-ún sẹ́wọ̀n l'Abẹ́òkúta


Ilu Abẹokuta, ipinlẹ Ogun ni wọn ti ju awọn marun-un ti ẹ n wo yii sẹwọn lori ẹsun jibiti ori ayelujara ti wọn n pe ni 'Yahoo-Yahoo' gẹgẹ bi ajọ EFCC ṣe ṣalaye.


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI