Bi ikọlu ilẹ Russia si Ukraine ṣe n fi ojoojumọ peleke si i, awọn oṣiṣẹ ologun orileede Ukraine ti bẹrẹ si i ki awọn mọlẹbi wọn wi pe 'o dabọ'.
Bi gbogbo wọn ṣe n lọ si oju ogun lo jẹ ki wọn ma a wo o pe o ṣee ṣe ki awọn ma le tun lanfaani lati foju kan wọn mọ, ti wọn si ti n lero wi pe o ṣee ṣe ki wọn gba oju ogun naa lọ sọrun aremabọ.
Adura awọn eeyan kaakiri agbaye bayii ni pe ki Ọlọrun da si wahala naa, ko si dawọ ogun duro.
No comments:
Post a Comment