Onidajọ Agatha A. Okeke tile ẹjọ giga apapọ to wa ni Uyo, l'Ọjọbọ, ọjọ kẹta oṣu keta, ọdun 2022 ti sọ Idongesit Samuel Eyibio sẹwọn ọdun meji lai si sisan owo itanran.
Eyibio ni ajọ EFCC gbe lọ si ile ẹjọ lọjọ kẹfa, oṣu keji, ọdun 2022 fun ṣiṣi awọn oṣiṣẹ ajọ naa lọna, ati fifi awọn ọrọ to ṣe pataki kan pamọ ninu iwe ifisun rẹ, eyi ti ile ẹjọ kan ti ṣe idajọ rẹ.
No comments:
Post a Comment