Dẹjọ Tunfulu ti ku oooooooo - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, April 1, 2022

Dẹjọ Tunfulu ti ku oooooooo


Iroyin to tẹ AWIKONKO lọwọ laaarọ oni, ọjọ Ẹti, Furaidee ti fidi rẹ mulẹ wi pe ọkan lara awọn agba ọjẹ nidii iṣẹ tiata, ẹni to tun jẹ adẹrinpoṣonu nni, Ọgbẹni Kunle Adetokunbọ ti ọpọ awọn eeyan mọ si Dẹjọ Tunfulu ti jade laye.

Ẹkunrẹrẹ alaye n bọ laipẹ

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI