Ọṣinbajo wọlu Ilọrin, o ṣabẹwo si Gomina AbdulRazaq ati Ẹmir ilu Ilọrin - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, May 16, 2022

Ọṣinbajo wọlu Ilọrin, o ṣabẹwo si Gomina AbdulRazaq ati Ẹmir ilu Ilọrin


Igbakeji Aarẹ orileede yii, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo lonii, ọjọ Aje, Mọnde ti ṣe abẹwo si Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara lori eto idibo to n bọ lọna.

Nibi abẹwo ọhun lo ti ya lọ ṣe abẹwo si Ẹmir tilu Ilọrin, Ọmọwe Ibrahim Sulu-Gambari, ẹni to tun jẹ alaga ẹgbẹ àwọn ọba alaye n'ipinlẹ naa.

Diẹ ree lara fọto abẹwo ọhun:No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI