AbdulRazaq ṣabẹwo akanṣe iṣẹ idagbasoke si Fáṣọlá - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, August 24, 2022

AbdulRazaq ṣabẹwo akanṣe iṣẹ idagbasoke si Fáṣọlá


Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara lọjọ Iṣẹgun, Tusidee ana ti ṣe abẹwo lori iṣẹ idagbasoke si minisita f'ọrọ eto akanṣe iṣẹ ati ilegbee, Ọlọlajulọ Babatunde Raji Faṣọla.

Yatọ si Faṣọla ti Gomina AbdulRazaq ṣabẹwo si, o tun ri minisita f'ọrọ eto akanṣe iṣẹ ipinlẹ, iyẹn State fir Works, Ọnarebu Ibrahim Umar El-Yakub.

Ilu Abuja la gbọ pe Gomina AbdulRazaq ti lọ yọju si wọn lati ba wọn ṣe ipade lori bi akanṣe iṣẹ awọn opopona Kishi si Kaiama, Ilọrin si Kabba, Ilọrin si Jebba, at'awọn opopona miran to wulo yoo ṣe di ṣiṣe lai fi akoko ṣofo.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI