Ẹ jẹ ka 'Buga Wọn' fun Gomina AbdulRazaq - Lateef Ọlamilekan - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, September 11, 2022

Ẹ jẹ ka 'Buga Wọn' fun Gomina AbdulRazaq - Lateef Ọlamilekan


Beeyan ba ṣe rere, ka wi, beeyan ba si ṣe ohun to ku diẹ kaato, a ni lati sọ faraye, eyi lo fa apilẹkọ ti Ọgbẹni Lateef Ọlamilekan kọ nipa Gomina AbdulRahman AbduRazaq t'ipinlẹ Kwara.
 
Ninu apilẹkọ ọhun lo ti yannanaa awọn aṣeyọri Gomina AbdulRazaq laaarin ọdun mẹta to gba ijọba kuro lọwọ awọn alatako.


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI