Wọn ju ọmọ 'Yahoo-Yahoo' mẹjọ ṣewọn ọdun mẹrindinlogun ni Benin - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, September 28, 2022

Wọn ju ọmọ 'Yahoo-Yahoo' mẹjọ ṣewọn ọdun mẹrindinlogun ni Benin


Awọn gendekunrin ti ko din ni mẹjọ ni iroyin ti fi to wa leti ile ẹjọ giga ti ipinlẹ Ẹdo ti ju ṣewọn ọdun mẹrindinlogun, lori ẹsun jibiti ori ikanni ayelujara ti a mọ si Yahoo-Yahoo.

Ọjọ Aje, Mọnde, ati ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii la gbọ pe wọn da ẹjọ awọn mẹjẹẹjọ pẹlu iṣẹ aṣekara.

Nigba to n gbe idajọ kalẹ, Onidajọ Efe Ikponwonba ati Onidajọ M. Itsueli ni wọn da awọn ẹjọ naa fun wọn.

Wọn da ẹjọ wọn lẹyin ti wọn gba pe àwọn jebi awọn ẹsun ti ajọ EFCC fi kan wọn.

Àwọn naa Nosa Osasuyi, Osayande Prosper, Egwabor Jim Uloma, Enofe Macaulay, Ige Damilola Oluwaseun, Omotehinse Joshua Oriade, Rawlings Nnaomi Nwabunwanne ati Temitayo TemenuTemitope. 

Siwaju, awọn miran Osasuyi, Prosper, Uloma, Nwabunwanne, Temitope, Macaulay, Oluwaseun ati Oriade 
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI