Okocha sọ aṣiri idi ti Qatar fi padanu sọwọ Ecuador - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, November 20, 2022

Okocha sọ aṣiri idi ti Qatar fi padanu sọwọ Ecuador


Balogun ikọ ẹgbẹ agbabọọlu Super Eagles tẹlẹ, Jay Jay Okocha ti sọ pe awọn ẹrọ amuletutu ti orileede Qatar ṣe sawọn papa iṣere wọn lo fa ijakulẹ ti wọn ba pade lonii, ọjọ Aiku, Sannde.
 
Okocha ni ẹrọ amuletutu, iyẹ Air Conditioner to wa ni papa iṣere Al Bayt, Al Khor, lo ṣee ṣe ko faa ti wọn fi padanu ifẹsẹwọnsẹ akọkọ wọn.
 
O wa be oṣuba kare fun orileede Ecuador pẹlu bi wọn ṣe lu Qatar ni alubami pẹlu aami ayo meji si oodo.
 
Nibi itakurọsọ to waye lẹyin ifẹsẹwọnsẹ naa, eyi ti Super Sport ṣagbatẹru ẹ ni Okocha ti sọrọ naa, to si ni iṣẹ takuntakun ni orileede Ecuador ṣe lonii.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI