Eto awọọdu opin ọdun fẹẹ waye fawọn to ṣe daadaa julọ ni Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, December 20, 2022

Eto awọọdu opin ọdun fẹẹ waye fawọn to ṣe daadaa julọ ni Kwara


Gbogbo eto lo ti fẹẹ pari patapata bayii fun ti akanṣe eto awọọdu ti ijọba ipinlẹ Kwara gbe kalẹ lati maa fi mọ riri awọn ọmọ ipinlẹ naa, paapaa awọn to n gbe orukọ wọn ga kaakiri agbaye.

Opin ọdun ni eto naa maa n waye, gẹgẹ bi agbekalẹ ijọba.

AWIKONKO gbọ pe ọjọ kẹtalelogun, oṣu kejila, ọdun 2022 ni eto ọhun yoo waye ni gbọngan ayẹyẹ Atlantic to wa loju ọna Ajaṣẹ Ipo, ilu Ilọrin.

Lati dibo, ikanni yii lẹ maa lo lati dibo fawọn ti ẹ ba fẹran: https://awards.kwarastate.gov.ng/

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI