Ijamba ọkọ tun waye l'Abẹokuta - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, January 19, 2023

Ijamba ọkọ tun waye l'Abẹokuta


Bo tilẹ jẹ pe a ko le sọ boya eeyan ku ninu ijamba mọto to waye lalẹ Ọjọru, Wẹsidee, ọsẹ yii, ṣugbọn ijamba naa le kọja bẹẹ to fi da sunkẹrẹ fakẹrẹ ọkọ silẹ.

Agbegbe Adedẹrọ ni ijamba naa ti waye ni nnkan bi aago mẹjọ alẹ

Awọn oṣiṣẹ aabo oju popona nipinlẹ Ogun, TRACE ni wọn palẹmọ ijamba naa kuro, ti wọn si dẹkun sunkẹrẹ fakẹrẹ.
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI