Jay-Jay Okocha ṣayẹyẹ igbeyawo ọdun marundinlọgbọn lara-ọtọ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, January 4, 2023

Jay-Jay Okocha ṣayẹyẹ igbeyawo ọdun marundinlọgbọn lara-ọtọ


Agba agbabọọlu nni to tun jẹ balogun ikọ ẹgbẹ agbabọọlu Super Eag;es ti orileede Naijiria tẹlẹ, Austin Jay-Jay Okocha lo ti ṣayẹyẹ ọdun marundinlọgbọn toun pẹlu ololufẹ rẹ ti gbe ara wọn sile.
 
Okocha lọ ṣayẹyẹ nla naa lọjọ Iṣẹgun, Tusidee to kọja yii pẹlu ara, ọrẹ ati mọlẹbi wọn wọn.
 
Ara-ọtọ la gbọ pe wọn gba ṣe ayẹyẹ naa, ti wẹjẹ-wẹmu si ṣẹlẹ pẹlu ariya rẹpẹtẹ.

Fọnran ayẹyẹ naa ree:

 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI