Ile ẹjọ to jokoo niluu Oṣogbo, ipinlẹ Ọṣun ti paṣẹ pe ki Ademọla Adeleke lọ rọkunle, ko si fi ipo gomina silẹ. O ni Gboyega Oyetọla lo jawe olubori ninu eto idibo to waye n'ipinlẹ naa lọjọ kẹrindilogun, oṣu keje, ọdun 2022.
Gomina ana, Gboyega Oyetọla lo wọ Adeleke lọ sile ẹjọ lati tako idibo to gbe e wọle gẹgẹ bii gomina.
Oyetọla ni gomina ipinlẹ Ọṣun tẹlẹ labẹ asia ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC, nigba ti Ademọla Adeleke jẹ gomina ipinlẹ naa lọwọlọwọ labẹ asia ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDP.
Ẹkunrẹrẹ iroyin n bọ laipẹ
It's not true
ReplyDeleteThat is a very big cheeting about removing ademola adeleke from governor of osun state all apc na rippers they are all ole especially tinubu and buari
ReplyDelete