Eyi ni bi Funkẹ Akindele ṣe padanu mama ẹ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, February 10, 2023

Eyi ni bi Funkẹ Akindele ṣe padanu mama ẹ


Gbajugbaja oṣerebinrin nni Funkẹ Akindele, ẹni t'ọpọ awọn eeyan tun mọ si Jẹnifa lo ti padanu mama ẹ lojiji.
 
Bo tilẹ jẹ pe ọpọ awọn eeyan ni wọn ti n ba Funkẹ to jẹ igbakeji oludije s'ipo gomina ipinlẹ Eko labẹ asia ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDP, ko sọ kulẹkulẹ iru iku to pa mama naa, sibẹ wọn ni aisan rampẹ lo mu ẹmi mama naa lọ.
 
Aburo Funkẹ, Olubunmi Akindele lo gbe iroyin naa sita loju opo Instagiraamu rẹ lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI