Ipolongo ibo aarẹ fun Peter Obi fori ṣanpọn l'Abẹokuta - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, February 9, 2023

Ipolongo ibo aarẹ fun Peter Obi fori ṣanpọn l'Abẹokuta


Ọrọ buruku toun tẹrin lọsẹ to kọja yii nigba ti ipolongo ibo aarẹ fun oludije s'ipo aarẹ orileede Naijiria labẹ asia ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDP foriṣanpọn.

Atigba ti Ọmọwe Doyin Okupe ti fẹgbẹ naa silẹ, to si loun ko le tẹsiwaju mọ gẹgẹ bi alaga olupolongo la gbọ pe wahala ti de ba ẹgbẹ naa.
 
Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, wọn ni ko si ọmọ ẹgbẹ kankan, to fi mọ awọn oloye ẹgbẹ to yọju sibi gbagede ipolongo naa to waye ni Ake, niluu Abẹokuta.
 
Fun bi ọpọ wakati la gbọ pe wọn fi duro de awọn eeyan lati wa, ṣugbọn to pada jẹ pe itiju ni wọn ba lọ.
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI