Komiṣanna lakoko iṣakoso Ahmẹd fontẹ lu AbdulRazaq lẹẹkeji - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, March 12, 2023

Komiṣanna lakoko iṣakoso Ahmẹd fontẹ lu AbdulRazaq lẹẹkeji


Ọkan pataki lara awọn kọmiṣanna to ba iṣakoso ana nipinlẹ Kwara ṣiṣẹ, Kalẹ Ayọ ti sọ pe oun fontẹ lu Gomina AbdulRahman AbdulRazaq lẹẹkeji.
 
Kọmiṣanna fọrọ eto ere idaraya ati awọn ọdọ ni Kalẹ Ayọ labẹ iṣakoso Gomina Abdulfatah Ahmed to gbe ijọba silẹ, ọkan pataki lara awọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDP si ni pẹluu.
 
Laipẹ yii ni ọkunrin naa kede sita gbangba wi pe oun ti lọ darapọ mọ ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC lati ṣatilẹyin fun Gomina AbdulRazaq fun saa keji.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI