Ọmọ ọdun mẹẹdogun poora l'Ekoo - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, April 10, 2023

Ọmọ ọdun mẹẹdogun poora l'Ekoo


Bi ẹ ṣe n ka iroyin yii, wọn ko tii ri ọmọdekunrin, ọmọ ọdun mẹẹdogun ti ẹ n wo yii, ẹni ti wọn loo dawati lojiji.

Owoṣeni Taiwo lorukọ ọmọ naa ti wọn lo wa ni SS 1, itẹn nile ẹkọ girama.

Adugbo Ewu-Ọwa Gberigberi to wa loju ọna Ijede, Ikorodu l'Ekoo ni wọn sọ pe Taiwo n gbe pẹlu awọn obi rẹ.

Bi ẹnikẹni ba kofiri rẹ nibikibi, ki wọn fi to ileese ọlọpaa to ba sunmọ wọn leti, tabi ki wọn pe mama rẹ, Arabinrin Owoṣeni Bọlanle sori 08143353778, tabi baba rẹ, Ọgbẹni Owoṣeni Ayọdele lori 08147433315.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI