Aarẹ Tinubu gbe oriyin fun ikọ ẹgbẹ agbabọọlu Flying Eagles - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, June 1, 2023

Aarẹ Tinubu gbe oriyin fun ikọ ẹgbẹ agbabọọlu Flying Eagles


Aarẹ Bọla Ahmẹd Tinubu ti gbe oriyin nla fun ikọ ẹgbẹ agbabọọlu Flying Eagles, lori bi wọn ṣe fidi ikọ ẹgbẹ agbabọọlu ti orileede Argentina gbolẹ laipẹ yii nibi ifigagbaga ife ẹyẹ agbaye ti awọn tọjọ ori wọn ko ju ogun ọdun lọ.
 
Tinubu lo gbe oriyin naa fun wọn laipẹ yii loju opo ikanni ayelujara rẹ, to si ni idunnu nla lo jẹ foun lati rii pe awọn agbabọọlu naa n gbe orileede wọn ga.
 
Flying Eagles lo lu Argentina lalubami pẹlu aami ayo meji si oodo lati yege fun ipele Quater Final, ninu idije to n lọ lọwọ yii.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI