Saa keji yii yoo so eso rere f'araalu - Gomina AbdulRazaq - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, June 1, 2023

Saa keji yii yoo so eso rere f'araalu - Gomina AbdulRazaq


Gomina AbdulRahman Abdulrazaq ti ṣalaye lẹkunrẹrẹ f'awọn ọmọ ati olugbe ipinlẹ Kwara nipa awọn akanṣe iṣẹ ati awọn ohun idagbasoke to fẹẹ ṣe ni saa keji rẹ yii, iyẹn lẹyin ti wọn bura fun un.
 
Nibi eto ayẹyẹ ibura to waye lọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii ni Gomina AbdulRazaq ti sọ pe saa keji ohun yii yoo so eso rere, ju ti atẹyinwa lọ fun gbogbo araalu, to si ni ki wọn lọ fọkan balẹ nitori pe iṣẹ n lọ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI