Irọlẹ ọjọ Aiku, Mọnde ana ni Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ṣabẹwo ibi ti iṣẹ de lori atunṣe odo Aṣa to n lọ lọwọ, lojuna lati dẹkun ijamba omiyale ati agbara ya ṣọọbu.
Nibi abẹwo naa ni gomina ti gba gbogbo araalu lamọran lati dẹkun dida idọti ai ilẹ sinu awọn kọta to n gbe omi, nitori pe o le fa ijamba omiyale to le mu ki wọn padanu ẹmi ati dukia wọn.
No comments:
Post a Comment