AbdulRazaq ṣabẹwo si ọsibitu awọn ọmọde n'Ilọrin, o ṣeleri atilẹyin fun wọn (Fọto) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, July 26, 2023

AbdulRazaq ṣabẹwo si ọsibitu awọn ọmọde n'Ilọrin, o ṣeleri atilẹyin fun wọn (Fọto)


Gomina ipinlẹ Kwara, AbdulRahman AbdulRazaq ti ṣe abẹwo si ọsibitu awọn ọmọde to wa lagbegbe Igboro niluu Ilọrin.

Nibi abẹwo ọhun ni gomina ti sọ pe oun fẹẹ wo bi iṣẹ ṣe n lọ si nibẹ, ati lati tun mọ awọn nnkan ti wọn nilo lati ọwọ ijọba.

Diẹ ree lara awọn fọto abẹwo ọhun:

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI