AbdulRazaq ra irinṣẹ igbalode tuntun fun tẹlifiṣan Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, November 25, 2023

AbdulRazaq ra irinṣẹ igbalode tuntun fun tẹlifiṣan Kwara


Lati le jẹ ki wọn ba ẹgbẹ pe lawujọ, Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara ti ra awọn irinṣẹ igbalode tuntun fun ileeṣẹ tẹlifiṣan ipinlẹ naa, Kwara State Television Authority (KWTV) lati le tubọ jẹ ki iṣẹ wọn munadoko.

Lara awọn irinṣẹ igbalode naa ni Vimix system with Configuration, Black Magic design Aten Television Studio Pro 4k switcher ati Black Magic Decklink Mini Monitor 4k.

Diẹ ree lara awọn irinṣẹ naaNo comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI