Doyin Okupe fẹgbẹ oṣelu Labour silẹ lojiji - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, January 8, 2024

Doyin Okupe fẹgbẹ oṣelu Labour silẹ lojiji


Gbajugbaja oloṣelu nni, Doyin Okupe ti kede sita gbangba wi pe oun ti fẹgbẹ oṣelu Labour silẹ, ati pe oun ko tun ni nnkan ṣe pẹlu ẹgbẹ naa mọ.
 
Ninu lẹta to fi ranṣẹ si Julius Abure, Okupe to ti figba kan ti jẹ olori igbimọ alakoso eto ipolongo idibo aarẹ ṣalaye lẹkunrẹrẹ nipa ohun to ṣokunfa bo ṣe fẹgbẹ ọhun silẹ.
 
Lẹta ọhun ree
 


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI