Wọn gbe oku Akeredolu wọ Naijiria lati Germany (Fọto) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, January 5, 2024

Wọn gbe oku Akeredolu wọ Naijiria lati Germany (Fọto)


Oku gomina ana nipinlẹ Ondo, Arakunrin Oluwarotimi Akeredolu ti balẹ si Naijiria.
 
Agogo mẹrin ku iṣẹju mọkandinlọgbọn, 3:39pm, ọjọ Ẹti, Fraide, ọjọ karun-un, oṣu kinni, ọdun 2024 ni wọn gbe oku naa de.

Iyawo rẹ, Betty Anyanwu-Akeredolu; awọn ọmọ ati awọn mọlẹbi ti Ọjọgbọn Wọle Akeredolu to jẹ aburo oloogbe lo lọ pade oku naa ni papakọ ofurufu.
 
Ọjọ kẹtadinlọgbọn, oṣu kejila, ọdun 2023 ni Akeredolu dagbere faye lẹyin aisan jẹjẹrẹ to ba a finra fun ọjọ pipẹ.

Awọn foto

 

Late Ondo governor, Rotimi Akeredolu
Late Ondo governor, Rotimi Akeredolu
Late Ondo governor, Rotimi Akeredolu
Late Ondo governor, Rotimi Akeredolu
Late Ondo governor, Rotimi Akeredolu
Late Ondo governor, Rotimi Akeredolu
Late Ondo governor, Rotimi Akeredolu

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI