Kwara: Wo awọn iranlọwọ ti Gomina AbdulRazaq ti ṣe f’awọn araalu sẹyin - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, February 26, 2024

Kwara: Wo awọn iranlọwọ ti Gomina AbdulRazaq ti ṣe f’awọn araalu sẹyin


Latigba ti eto ọwọngogo ti bẹrẹ kaakiri Naijiria ni Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara ti gbe oriṣiriṣi eto iranwọ dide fun awọn araalu.

Yatọ si ti baagi irẹsi kilogiraamu mẹwaa to pin fawọn araalu lasiko ti igbe aye ko rọrun fun araalu, gomina tun gbe awọn eto miran kalẹ ti yoo mu igbe aye rọrun faraalu.

Lara wọn si ni;

1. Dry Season Farmers' Support: ₦1,000,000 each to 150 farmers

2. Social Safety Net: ₦10,000 for 60,000 beneficiaries 

3. Widows Support: ₦20,000 for 20,000 beneficiaries 

4. Public Workfare: ₦10,000 for 16,000 beneficiaries 

5. Petty Traders: ₦20,000 for 11,000 beneficiaries 

6. Public Workfare (Environmental Task Force): ₦30,000 for 20 beneficiaries 

7. Business Groups Empowerment: ₦3,000,000 for 20 groups

8. Kwapreneur 4.0: ₦200,000 - 2,000,000 for 368 SMEs

9. Skilled and Unskilled: ₦50,000 for 4,000 beneficiaries 

10. Public Workfare (Youths): ₦25,000 for 8,000 beneficiaries 

11. Household Support Program: ₦30,000 for 5,000 beneficiaries

The following road projects have also commenced as several others near completion:

1. Bukka Adena Bridge, Kaiama 
2. ⁠Ilesha Baruba - Gwanara Road 
3. ⁠Adeta - Oloje Road 
4. ⁠Unity Bridge
5. ⁠Wahab Folawiyo Road 
6. ⁠Town Hall Road, Igbaja 
7. Construction Of 4m X 2m Culvert along Shao- Malete Road, Moro 
8. ⁠Egberiomo Bridge, Moro
9. ⁠Isale Jagun - Kuntu Road
10. Construction of Master Drainage along Dada - Aiyegbami road, Ilorin

Bakan naa, Gomina AbdulRazaq tun ni ki iṣẹ akanṣe bẹrẹ lori awọn ọna ti awọn araalu n beere fun, bii;

1. Construction of interlock access road at Mafeolaku-Oke Aluko Secondary School linking Taiwo Road in Okaka Ward

2. ⁠Construction Of Interlock Access Road, At Ile Ipapo – Kajola – Asamu Street, Ilorin

3. Construction Of Interlock access Road, At Amuda Aluko – Apabiekun – Kanike Area

4. ⁠Construction Of Interlock Access Road, At Ita Ogunbo Oke-kokorokan – Jaji Area

5. ⁠Construction Of Interlock Access Road, At Masalasi Gogoro – Isowo – Abemi – Popo Giwa – Ita Egba Area

6. ⁠Construction Of Interlock Access Road, Along Mama Area, Off Adabata

7. ⁠Construction Of Interlock Pavement Along Oniboki Area, Asa

Ajọ UNICEF dide iranwọ eto ilera ẹgbẹrun lọna ẹẹdẹgbẹta owo dọla ni Kwara

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI