Olukọya, olori ijọ MFM lagbaye ṣi ṣọọṣi tuntun mẹjọ niluuu Abẹokuta - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, April 29, 2024

Olukọya, olori ijọ MFM lagbaye ṣi ṣọọṣi tuntun mẹjọ niluuu Abẹokuta


Alaṣẹ ati oludasilẹ ijọ Mountain of Fire and Miracles Ministries (MFM) lagbaye, Ọmọwe Daniel Kọlawọle Olukọya ti ṣi ẹka ijọ naa tuntun mẹjọ niluu Abẹokuta, ipinlẹ Ogun.

Ọmọwe Olukọya lo gbe ikede naa sita loju opo ayelujara ti Facebook rẹ lọsan oni, nibi to ti jẹ ko di mímọ pe iṣẹ Oluwa n tẹsiwaju.O ni ijọ Ọlọrun n tẹsiwaju ninu iṣẹgun ologo nla, ati pe ilẹkun ọrun apaadi ko le bori rẹ.


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI