Ijọba Naijiria gbẹsẹ pe dukia Emefiele, wọn tun ba biliọnu marun-din diẹ owo dọla lọwọ ẹ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, May 24, 2024

Ijọba Naijiria gbẹsẹ pe dukia Emefiele, wọn tun ba biliọnu marun-din diẹ owo dọla lọwọ ẹ


Ile-ẹjọ giga agba ti sọ pe ohun gbẹsẹ le owo to din diẹ ni biliọnu marun-un owo dọla ($4.72m), miliọnu lọna ẹgbẹrin le diẹ (N830.88m) naira, to fi mọ dukia to le ni obitibiti biliọnu, eyi to jẹ ti gomina ana fun banki aoapọ ilẹ wa, CBN, Godwin Emefiele.

Onidajọ Yellim Bogoro lo paṣẹ naa l'Ọjọbọ, ọsẹ yii lasiko to n gbọ ẹjọ ti ajọ EFCC tako o lori ẹsun jibiti ti wọn fi kan an.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI