Àwòrán ilé ìwòsàn ICU tó tóbi jùlọ ní ẹkùn àárín gbùngbùn Àríwá Nàìjíríà - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, February 6, 2025

Àwòrán ilé ìwòsàn ICU tó tóbi jùlọ ní ẹkùn àárín gbùngbùn Àríwá Nàìjíríà


Titi di asiko yii ni awọn eeyan kaakiri agbaye ṣi n sọrọ nipa ile iwosan igbalode, ẹka ICU tii ṣe Intensive Care Unit to wa nipinlẹ Kwara.

Gomina AbdulRahman AbdulRazaq lọ kọ ẹka ile iwosan ti wọn ti n tọju awọn alaisan naa si ọsibiti awọn olukọni to wa niluu Ilọrin.

Iyawo Aarẹ Naijiria, Sẹnetọ Olurẹmi Tinubu lo lọ ṣiṣọ loju ile iwosan naa lasiko abẹwo to ṣe si ipinlẹ Kwara .

#IṣẹNtẹsiwaju


































































No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI