Ọgagun agba ni 22 Armoured Brigade to wa niluu Sobi, Brigadier General Ezra Barkins; Olorin oṣiṣẹ ologun, Lieutenant General Olufemi Olatubosun Oluyede; ati alakoso agba ni Commanding 2 Division of the Nigerian Army to wa niluu Ibadan, ipinlẹ Oyo, General Obinna Onubogu lawọn to ṣabẹwo siluu Ilorin.
Nibẹ ni wọn ti ṣeleri pe gbogbo adojukọ to n koju eto aabo nipinlẹ naa lawọn yoo wa iyanju si.
No comments:
Post a Comment