Ni ibamu pẹlu ilana eto ilera agbaye, ati lati ni ẹkọ kikun lori itọju ẹmi awọn araalu, ijọba ipinlẹ Kwara pẹlu ajọṣepọ ajọ United Nations Population Fund (UNFPA), ti ṣagbekalẹ idanilẹkọọ ọlọjọ mẹrin gbako fawọn oṣiṣẹ eleto ilara jakejado ipinlẹ naa.
Ajọ UNFPA to wa labẹ akoso European Union Strengthening Access to Reproductive and Adolescent Health (EU SARAH) Project, la gbọ pe wọn ti bẹrẹ eto idanilẹkọọ naa bayii, kaakiri ijọba ibilẹ mẹrindinlogun to wa ni Kwara.
Idanilẹkọọ ọhun, gẹgẹ bi a ṣe gbọ, lo da lori awọn ohun ti wọn pe ni Revised Contraceptive Logistics Management System (CLMS) ati Nigeria Health Logistics Management Information System (NHLMIS) fun State Reproductive/ Family Planning, Logistics Management and Coordination Unit and Family Planning.
The training, which kicked off yesterday in Ilorin, is aimed at strengthening the logistics and data management capacity of key personnel, responsible for family planning across the state.
Nigba to n sorọ nibi iṣide idanilẹkọọ naa, Kọmiṣanna feto ilera, Dokita Amina Ahmed El-Imam, sọ pe lojuna lati jẹ ki awọn oṣiṣẹ eleto ilera mọ pataki ifeto sọmọ bibi, paapaa lawọn ona to fẹẹ le koko ni idanilẹkọọ ọhun wa fun.
No comments:
Post a Comment