Ìjọba Kwara ṣàgbékalẹ̀ àsíá tó tóbi jùlọ lẹ́kùn ìwọ̀ oòrùn Áfríkà sí Ìlọrin - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, May 16, 2025

Ìjọba Kwara ṣàgbékalẹ̀ àsíá tó tóbi jùlọ lẹ́kùn ìwọ̀ oòrùn Áfríkà sí Ìlọrin

 

Itan tuntun ni ipinlẹ Kwara tun fi balẹ lẹkun iwọ oorun ilẹ Afrika pẹlu bi wọn ṣe ṣagbekalẹ opo asia to tobi julọ lẹkun naa.

 Agbekalẹ tuntun yii la gbọ pe yoo tun mu awọn eeyan kaakiri agbaye wọ ipinlẹ naa fun irin ajo afẹ.

Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, aadọrin mita ni opo ọhun to di asia orileedẹ Naijiria mu jẹ, leyi to mu ko jẹ eyi to ga julọ lẹkun irọ oorun Afrika. 

Aarin gbungbun ipinlẹ Kwara, nibi ti eto ọrọ aje ti n rọṣọmu ni ijọba Kwara gbe opo asia naa si, leyi to n ṣafihan apejẹ awọn Kwara.

Opo asia naa lo jẹ ohun idanimọ ati iwuri ilẹ Naijiria.



No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI