Gomina AbdulRazaq ṣabẹwo s'awọn olujọsin to gba itusilẹ kuro lọwọ awọn ajinigbe ni Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, November 24, 2025

Gomina AbdulRazaq ṣabẹwo s'awọn olujọsin to gba itusilẹ kuro lọwọ awọn ajinigbe ni Kwara


Inu mi dun lati kede itusilẹ awọn mejidinlogoji to gba ominira kuro lakata awọn ajinigbe, iyẹn awọn olujọsin ti wọn ṣe ikọlu si nile ijọsin Christ Apostolic Church (CAC) Eruku, ijọba ibilẹ Ekiti LGA nipinlẹ Kwara. Eyi lo waye lẹyin ọpọlọpọ ọjọ ti awọn eleto aabo fi ṣiṣẹ," Gomina AbdulRahman AbdulRazaq lo sọ bẹẹ nigba to n ki awọn eeyan ilu Eruku.

Gomina AbdulRahman AbdulRazaq dupẹ lọwọ Aarẹ Bola Ahmed Tinubu lori igbesẹ ti wọn fi gba awọn olujọsin naa silẹ.




No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI