Olohungbebe di alaga ajọ NEC nilẹ Naijiria - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, December 10, 2025

Olohungbebe di alaga ajọ NEC nilẹ Naijiria


Kọmiṣanna feto ẹkọ nilẹ Naijiria, Ọmọwe Lawal Olohungbebe ti di alaga apapọ fun igbimọ to n ri sọrọ eto ẹkọ nilẹ Naijiria, Committee of State Commissioners of Education (COSCEN).

Olohungbebe ni yoo tukọ fun saa tuntun.

Nibi eto ibura to to waye nileeṣẹ UBEC to wa niluu Abuja, ni Olohungbebe ti gbe oriyin fun Gomina AbdulRahman AbdulRazaq lori ipa to ko lati jẹ ki ipo naa ja mọ oun lọwọ.

Lara awọn to wa nibi eto ibura naa ni awọn bii Minisita feto ẹkọ nilẹ Naijiria, Ọmọwe Tunji Alausa; Ọjọgbọn Suwaiba Said Ahmad, akọwe ajọ UBEC; ati Ọmọwe Aisha Garba, to fi mọ awọn Kọmiṣanna feto ẹkọ kaakiri Naijiria.



No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI