Awọn olori ẹsin Musulumi ati Kristẹni rọjo adura le Akewejẹ Olayinka Fafoluyi lori ni Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, March 19, 2026

Awọn olori ẹsin Musulumi ati Kristẹni rọjo adura le Akewejẹ Olayinka Fafoluyi lori ni Kwara


Beeyan ba wa nibi ti awọn olori ẹsin ti n gbadura fun amugbalẹgbẹ pataki fun gomina lori eto iroyin igbalode nipinlẹ Kwara, Akewejẹ Olayinka Fafoluyi, yoo mọ pe ohun to tọ ni ọkunrin naa ṣe.

Akewejẹ Fafoluyi lo pe akanṣe eto iṣinu aawẹ fun gbogbo awọn Musulumi ati Kristẹni ni wọọdu Ipetu/Rore/Aran-Orin.

Nibẹ ni wọn ti lo anfaani naa lati gbadura fun Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ati Akewejẹ funra rẹ.

Ọpọ awọn olori ẹsin Musulumi ati ti ajọ CAN ni wọn wa nibi apejẹ naa.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI