Ọba Sonuga, Daniyan keji lo n ṣayẹyẹ ọjọ ibi ọdun mẹrindinlaadọrun loke eepẹ.
Ninu atẹjade ti Bọrọkinni ilu Ilisan Remo, Aarẹ EmmanuelKing fi sita, o ṣapejuwe Kabiyesi naa gẹgẹ bi apejuwe alaafia, imọ, itẹsiwaju ati aṣaaju rere, ti asiko rẹ ti n.mu ibọwọ ati idagbasoke ba gbogbo Ilisan Remo.
Gẹgẹ bo ṣe sọ, Aarẹ EmmanuelKing sọ pe latigba ti Ọba alaye naa ti gun ori itẹ awọn baba nla rẹ, ni Kabiyesi ti n lo ipo adari rẹ lati fi farajin fun iṣọkan, idagbasoke ati itẹsiwaju aṣa nilẹ naa.
No comments:
Post a Comment